Kristi Imole t‘o da wa sileÀpẹrẹ

Kristi Imole t‘o da wa sile

Ọjọ́ 3 nínú 7

Ìṣẹgun Ti Òdàju

Nigbati wiwa Oluwa bá jẹ́ afojusun rẹ to ṣe pataki nini idapọ pẹlu Rẹ yóò jẹ ohun idunnu fún Ọ, ōkaniwa pẹlu Rẹ. Oluwa yíò wá pẹlu rẹ na.

Orin dafidi 91:1

[1]ẸNITI o joko ni ibi ìkọkọ Ọga-ogo ni yio ma gbe abẹ ojiji Olodumare.

Ìṣẹgun rẹ daju nitori ẹni tí owá pẹlu ati ìbí tí owá. Ti obá wá pẹlu Ọlọrun afi ọ pámó sínú Rẹ asiti gbé ọ gá jù ogun ọta to dótì ọ ka. Ọlọrun amā dābobo asi ma paòmọ́ ni gbogbo igba.

Ti Oluwa ba wa pẹlu rẹ tani ẹni tó lè dójú ìjà kō.

Iwọ yóò yọ, wã sí yin Ọlọrun ni iṣẹgun lori awọn Ọta rẹ.

Oluwa rán mi lọwọ láti dúró nínú ìgboyà rẹ titi ti iṣẹgun mi yíò f'ẹsẹ múlẹ.

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Kristi Imole t‘o da wa sile

Fun gbogbo àkókò òkunkun - ibẹrubojo ati sáà ìyè meji, àkò le ṣe alaimanilo imọlẹ gidgidi ni oniruru ọna. Láti fún wa ní Òye nípa ipò tí a wá tabi ọgbọn fún ìyípadà ilakọja ti ko dára fún réré. Eleyi ni jesu wá sí ayé láti musẹ. O sọ nínú ọrọ iṣẹ rẹ wípé "Emi ni imọlẹ aiye; ẹniti o ba tọ mi lẹhin kì yio rìn ninu òkunkun Johanu 8:12.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Adeoye Gideon fún pípèsè ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí i, jọ̀wọ́ lọ sí: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL