Bí A (Kò) Ṣe Lè Gba Ayé Là: Òtítọ́ Nípa Fífi Ìfẹ́ Ọlọ́run Hàn Sí Àwọn Ènìyàn Tí Ó Wà Ní Ẹ̀gbẹ́ẹ̀ RẹÀpẹrẹ

How (Not) to Save the World: The Truth About Revealing God’s Love to the People Right Next to You

Ọjọ́ 5 nínú 5

Bi (akò) ṣe lè gba ayé la: Mó ń ṣe àdáshe nígbà gbogbo

Nígbà tí mo kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìránsẹ́ mi, ó lé ní ọdún mẹ́rin tí mo fí rìn ìrìn àjò lọ sí onírúurú ṣọ́ọ̀ṣì àti àwọn ayẹyẹ́ káàkiri orílẹ̀-èdè náà. Mo jẹ́ àlejò ni ile àwọn ènìyàn orísirísi ni àkókó yì àti pé emi kò fẹ́ láti dúró kọjá ọjọ́ tí wọ́n gbà mí láyè láti ló. Mo ti ṣe alábápàdé Sean ati Shelley tẹ́lẹ̀ rí. Wọ́n pè mí láti ṣe eré fún ọ̀sẹ̀ márùn fún ayẹyẹ́ ṣọ́ọ̀ṣì wọn àti pé èmi yíò dúró sí iyàrá àlejò nínú ilé wọn. Nwọ́n sì mu mi gẹ́gẹ́bí ẹbi. Bí wọ́n ṣe túbọ̀ ń ṣe aájò àlejò mi, bẹ́ẹ̀ náà ni mo ṣe rò pé wọ́n jẹ́ aṣiwèrè tó. Èmi kò nílò ìrànlọ́wọ́ wọn tàbí àánú wọn—Mo mọ bí mo ṣe lè wà láàyè fúnra mi. Iṣẹ́ nìkan ni mo wá ṣe níbí. Mo gbìyànjú láti tá kété sí wọn.

Nígbàtí mo pinnu láti bọ si ìlànà iṣẹ́ yí jẹ akokò tí èmi kò ní ìmọ̀lára wípé èmi kò ní alátilẹyin rárá àti pé mo tó tán, ṣùgbọn ajagún ni mí. Mo ti ṣe ìjẹ́ri fún ará mi leralera wípe mo le ṣe àwọn nkán jú ọ̀pọ̀lọpọ̀ èniyàn lọ. Àti fá àwọn ènìyàn mọra yíò fà ìfàsẹ́hin fún mi, àti wípe mo máa tó kúrò ni ile Sean àti Shelley ni oṣù kán sì lọ́nàkọnà.

O gbà mi ni ọ̀pọ̀ ọdún láti ni òye òún ti o yẹ kí ń ti mọ̀ síwájú ní gbogbo ìgbésí ayé mi: Àdáṣhe nígbà gbogbo? Ìyẹn (kìí ṣe) ọ̀nà láti gba àgbáyé là. Òtítọ ní wípe a kólé dá nìkan mú àwọn ìpinnu Ọlọ́run ṣẹ ní kíkún fún ìgbésí ayé wa láti di ẹni ti O pinnu fún wa láti jẹ́. Àwùjọ le jẹ́ nkan ti o nira. Púpọ nínú wa ni a ti sopọ̀ mọ àwùjọ ti o si mú ìpalára bá wà, àti wípé a kò fẹ láti gbẹkẹlé àwọn ènìyàn tí yóò mú wá ṣìnà. Àti wípé a ti pinnu wípé a le da ẹrù wá gbé ti o ba dojú ẹ.

Ẹlẹ́dà àgbáyé dá wa láti wà ní àwùjọ—pẹ̀lú Ọlọ́run àti pẹ̀lú ara wa. Àjọṣepọ̀ àwùjọ kìí ṣe àṣàyàn fún wa. O ṣe pàtàkì ki ìgbésí ayé wa de ibi tí aṣẹ̀dá fún wa ní okun ati agbára de. Àwùjọ n fún wa ní agbára kìí ṣe láti parí àwọn iṣẹ-ṣiṣe tí Ọlọrun tí pe wá sí nikan, ṣùgbón láti di ẹni ti Ó dá wa láti jẹ. Ọtá náà si mọ èléyí pẹ̀lú. Ó fẹ́ kí á gba irọ́ náà gbọ́ wípé a kò nílò àwùjọ.

Sean àti Shelley fi hàn mí bí àwùjọ kan tó dá lórí Jésù gan-an ṣe lè rí gan-an. Mo wá rí i pé mo lè dá ṣe ayé ṣùgbọ́n mi ò lè fi gbogbo ara ṣègbọràn sí Ọlọ́run láìjẹ́ kí ìbádọ́rẹ̀ẹ́ gidi wọlé. Wọn kọ mi pe mo le jẹ apakan ti ṣiṣẹda iru agbegbe ti mo ngbadura fun.

Nígbàtí Ọlọ́run bá fi ẹnìkan si ìgbésí ayé rẹ, máṣe páátí. Tí ó ba ṣe bẹ́, ìwọ yíò pàdánù lórí oríṣiríṣi àwọn ìbásepọ̀ olùfúnni-ni-ìyè àyíká tí o lè gbe ọ ró ti yíò sì fún ọ lókun. Kọjú ìjà sí àdánwò tí ó lè fa ìdiwọ ohun ti Ọlọ́run fẹ láti ṣe nínú rẹ àti nípasẹ ìgbésí ayé rẹ àti nípasẹ àwọn ènìyàn Rẹ̀ pẹ̀lú.

Fún ọpọlọpọ wa igbesẹ akọkọ ni lati bẹrẹ gbigba ati bẹrẹ bibeere. Pinnu pe ó tọ́ láti mú wíwá sáyé rẹ ṣiṣẹ́, ati pe niwọn igba ti agbegbe ti fun u lokun, o tọ lati mu eewu fun ati igbesẹ si. Ti a ba pinnu lati ṣe igbesi aye nikan, a kii yoo dara julọ wa. Ile ijọsin jẹ ero Jesu’ lati de agbaye ti o nilo Rẹ ni pataki. Bi a ṣe jẹ iṣọkan diẹ sii, ipa wa yoo pọ si. Olorun n pe wa, Ijo Re, lati ba A se alabaṣepọ lori ise Re lati gba aye la.

Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ wá igbesẹ àkọkọ ní láti bẹ̀rẹ̀ síi máà gbà àti láti béèrè. Pinnu pé ó tọ́ láti mú wíwá sáyé rẹ ṣiṣẹ́, àti pe níwọ̀n ìgbà tí àwùjọ ńfún u ni òkun, o tọ láti dàya dé ewukewu àti láti tẹ́ síwájú. Ti a ba gbèrò láti dá ṣe ìgbésí ayé, a kò lè dé ojú òṣùwọ̀n kíkún. Àgbékalẹ̀ ìjọ jẹ ètò Jésù láti dé ile ayé tí ó fi ìtara nílò Rẹ̀. Bi ìṣọ̀kan wá ba ṣe danmoran to, bẹ́ẹ̀ni ipá wa yíò ṣe lágbára tó. Ọlọ́run ń pè wá, àti Ìjọ Rẹ̀, láti ṣe àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Rẹ̀ lórí iṣẹ́ àpínfúnni Rẹ̀ láti gba ayé là.


Dáhùn

Kí nìdí tó fi máa ń ṣòro nígbà míràn láti kópa nínú àwùjọ?

Báwo ní o ṣe lè ni àsopọ díẹ sii ni ojúlówó awujọ ti àwọn ọmọlẹyìn Jésù ti o fara jí? Báwo ni o ṣe le jẹ ọkàn nínú àwọn ti nkọ irú àwùjọ bẹ́ẹ?

Ta ní ẹni náà tí iwọ le ni ìgboyà láti súnmọ kí o sopọ pẹlú?


Bi (aò) ṣe lè gba ayé la: Máà dá fo nigbàgbogbo

Nígbà tí mo kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òjíṣẹ́ mi, ó lé ní ọdún mẹ́rin láti rìnrìn àjò lọ sí onírúurú ṣọ́ọ̀ṣì àti àwọn ayẹyẹ́ káàkiri orílẹ̀-èdè náà. Mo jẹ́ àlejò ni àwọn ile àwọn ènìyàn orísirísi ni àkókó yìí àti pé emi kò fẹ́ láti dúró kọjá itẹwọgbà mi. Síwájú ní mo ti pàdé Sean ati Shelley. Wọ́n pè mí láti ṣe eré fún ọ̀sẹ̀ márùn-ún ayẹyẹ́ ṣọ́ọ̀ṣì wọn àti pé èmi yóò dúró sí iyàrá àlejò nínú ilé wọn. Nwọ́n sì mu mi gẹ́gẹ́bí ẹbi. Bí wọ́n ṣe túbọ̀ ń ṣe aájò àlejò sí mi, bẹ́ẹ̀ náà ni mo ṣe rò pé wọ́n jẹ́ aṣiwèrè tó. Mi ò nílò ìrànlọ́wọ́ wọn tàbí àánú wọn—Mo mọ bí mo ṣe lè wà láàyè fúnra mi. Mo wá síbí fuyn ìṣẹ nìkan ní. Mo gbìyànjú láti fi wọn si òkèèrè.

Nígbàtí mo ṣe ìpinnu láti bọ si oju-ọnà yíì jẹ akokò ti alátilẹyin dá páu jùlọ lára mi, ṣùgbọn ajagún ni mí. Mo ti ṣe ìjẹ́ri fún ará mi leralera wípe mo le ṣe àwọn nkán díẹ síi jú ọ̀pọ̀lọpọ̀ èniyàn lọ. Àti fá àwọn ènìyàn mọra yíò ṣe ìfàsẹ́hin fún mi, àti wípe mo tó máa kúrò ni ile Sean àti Shelley ni oṣù kán pàápa.

O gbà mi ni ọ̀pọ̀ ọdún láti mọ òye òún ti o yẹ kí mo ti mọ̀ síwájú ní gbogbo ìgbésí ayé mi: O ń dá fo nigbàgbogbo? Ìyẹn (kìí ṣe) ọ̀nà láti gba àgbáyé là. Òtítọ ní wípe a kólé dá nìkan mú àwọn ìpinnu Ọlọ́run ṣẹ ní kíkún fún ìgbésí ayé wa láti di ẹni ti O pinnu fún wa láti jẹ́. Àwùjọ le jẹ́ nkan ti o nira. Púpọ nínú wa ni a ti sopọ̀ mọ àwùjọ ti o kàn wa ní égbo pupọ, àti wípé a kò fẹ láti gbẹkẹlé àwọn ènìyàn ti kò tọ. Àti wípé a ti pinnu wípé a le da nikan ye ti o ba dojú ẹ.

Ẹlẹ́dà àgbáyé dá wa láti wà ní àwùjọ—pẹ̀lú Ọlọ́run àti pẹ̀lú ara wa. Àjọṣepọ̀ àwùjọ kìí ṣe ìyàn. O ṣe pàtàkì ki ìgbésí ayé de kíkún ìwọn rẹ. Àwùjọ n fún wa ní agbára kìí ṣe láti parí àwọn iṣẹ-ṣiṣe nìkan tí Ọlọrun tí pe wá si, ṣùgbón láti di ènìyàn ti O dá wa láti jẹ. Ọtá na si mọ èléyí. Ó fẹ́ kí á gba irọ́ náà gbọ́ wípé a kò nílò àwùjọ.

Sean àti Shelley fi hàn mí bí ojúlówó àwùjọ tí ó jẹ́ ojúlówó Jesu tí lè rí. Mo wá rí i wípé mó le da ṣe àye ṣugbọn mí kò lè ṣègbọràn sí Ọlọ́run tàratára, láìjẹ́ kí àwọn ọ̀rẹ́ tòótọ́ súnmọ́. Wọ́n kọ́ mi wípé mo le jẹ́ ara iṣẹ̀da irú àwùjọ ti mò ngbà l'adura.

Nígbàtí Ọlọ́run bá fi ẹnìkan si ìgbésí ayé rẹ, máṣe àibìkità. Tí o ba ṣe bẹ́, ìwọ yíò pàdánù lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ore-ọfẹ pàtàkì tí o lè tayọ láárín ìbaṣepọ àyíká tí o lè gbe ọ sókè ti yíò fún ọ lókun. Takò ogun tíó lè fa ìdiwọ ohun ti Ọlọ́run fẹ láti ṣe nínú rẹ àti nípasẹ ìgbésí ayé rẹ àti nípasẹ àwọn ènìyàn Rẹ̀.

Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ wá igbesẹ àkọkọ ní láti bẹ̀rẹ̀ síi má gbà àti láti bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ìbéèrè. Pinnu pé kókó ìṣeda rẹ tọ láti gbéra nlẹ̀, àti pe níwọ̀n ìgbà tí àwùjọ ńfún u ni òkun, o tọ láti dàya dé ewukewu àti láti ṣe ìgbésẹ síwájú rẹ̀. Ti a ba pinnu láti dá ṣe ìgbésí ayé, a kì yíò jẹ irú ẹdá réré ti o dára jùlọ láé. Ìjọ jẹ ètò Jésù láti dé ile ayé tí ó taratara nílò Rẹ̀. Bi a bá ṣe ṣọ̀kan díẹ síi, bẹ́ẹ̀ni ipá wa yíò ṣe q pọ si. Ọlọ́run ń pè wá, Ìjọ Rẹ̀, láti ṣe àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Rẹ̀ lórí iṣẹ́ àyànfúnni Rẹ̀ láti gba ayé là.


Dáhùn

Kí nìdí tó fi máa ń ṣòro nígbà míì láti kópa nínú àwùjọ?

Báwo ní o ṣe lè ni àsopọ díẹ sii ni awujọ òdodo ti àwọn ọmọlẹyìn Jésù? Báwo ni o ṣe le jẹ ọkàn nínú àwọn ti nkọ irú àwùjọ bẹ́ẹ?

Ta ní ẹnìkan tí iwọ le ni ìgboyà láti súnmọ kí o sopọ pẹlú?


Njẹ́ ìwọ fẹ́ láti mọ̀ jinlẹ jinlẹ síi bi o ṣe lè ja fún àwọn ti o nífẹ si, kí o si tun dàgbà sii nínú ìgbàgbọ rẹ?
Ṣe ìgbàsílẹ̀ ìpín ọ̀fẹ tiBi (aò) Ṣe lé Gba Ayé La& kọ ẹ̀kọ́ díẹ sii nípa iwe náa níbi:
www.hosannawong.com/savetheworld.


Nípa Ìpèsè yìí

How (Not) to Save the World: The Truth About Revealing God’s Love to the People Right Next to You

Ṣé o fẹ́ jà fún àwọn ènìyàn tí o fẹ́ràn kí o sì fi han àwọn ẹlòmíràn bí wọ́n ṣe ní iye l'órí tó sí Ọlọ́run? Nínú ètò kíkà ọlọ́jọ́ 5 yìí, tí ó dá l'órí ìwé Hosanna Wong How (Not) to Save the World, ṣe àwárí àwọn irọ́ tí ó ń dí ọ l'ọ́wọ́ l'áti ní ìfẹ̀ẹ́ àwọn ẹlòmíràn bí Ọlọ́run ṣe pè ọ́ sí. Gba àkókò l'áti ṣe àwárí ìfìwépè Jésù l'áti mọ̀ On, kí o pín-In pẹ̀lú áwọn ẹlòmíràn nípasẹ ìrírí aláìlẹ́gbẹ́ rẹ.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ HarperCollins/Zondervan/Thomas Nelson fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síi, jọ̀wọ́ ṣe àbẹ̀wò: https://bit.ly/savetheworldyouversion