Nítòótọ́, èmi kì yóò wọ inú àgọ́ ilé mi lọ, bẹ́ẹ̀ èmi kì yóò gun orí àkéte mi: Èmi kì yóò fi oorun fún ojú mi, tàbí òògbé fún ìpéǹpéjú mi, Títí èmi ó fi rí ibi fún OLúWA, ibùjókòó fún Alágbára Jakọbu.
Kà Saamu 132
Feti si Saamu 132
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 132:3-5
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò