Saamu 132:3-5

Saamu 132:3-5 YCB

Nítòótọ́, èmi kì yóò wọ inú àgọ́ ilé mi lọ, bẹ́ẹ̀ èmi kì yóò gun orí àkéte mi: Èmi kì yóò fi oorun fún ojú mi, tàbí òògbé fún ìpéǹpéjú mi, Títí èmi ó fi rí ibi fún OLúWA, ibùjókòó fún Alágbára Jakọbu.