Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

O. Daf 132:3-5

O. Daf 132:3-5 Bibeli Mimọ (YBCV)

Nitõtọ, emi kì yio wọ̀ inu agọ ile mi lọ, bẹ̃li emi kì yio gùn ori akete mi; Emi kì yio fi orun fun oju mi, tabi õgbe fun ipenpeju mi, Titi emi o fi ri ibi fun Oluwa, ibujoko fun Alagbara Jakobu.

Pín
Kà O. Daf 132

O. Daf 132:3-5 Yoruba Bible (YCE)

tí ó ní, “N kò ní wọ inú ilé mi, bẹ́ẹ̀ ni n kò ní bọ́ sí orí ibùsùn mi; n kò ní sùn, bẹ́ẹ̀ ni n kò ní tòògbé, títí tí n óo fi wá ààyè fún OLUWA, àní, tí n óo fi pèsè ibùgbé fún ìwọ Alágbára, Ọlọrun Jakọbu.”

Pín
Kà O. Daf 132

O. Daf 132:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

Nítòótọ́, èmi kì yóò wọ inú àgọ́ ilé mi lọ, bẹ́ẹ̀ èmi kì yóò gun orí àkéte mi: Èmi kì yóò fi oorun fún ojú mi, tàbí òògbé fún ìpéǹpéjú mi, Títí èmi ó fi rí ibi fún OLúWA, ibùjókòó fún Alágbára Jakọbu.

Pín
Kà O. Daf 132
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò