O. Daf 88:16-18

O. Daf 88:16-18 YBCV

Ifẹju ibinu rẹ kọja lara mi; ìbẹru rẹ ti ke mi kuro. Nwọn wá yi mi ka li ọjọ gbogbo bi omi: nwọn yi mi kakiri tan. Olufẹ ati ọrẹ ni iwọ mu jina si mi, ati awọn ojulumọ mi ninu okunkun.