ORIN DAFIDI 88:16-18

ORIN DAFIDI 88:16-18 YCE

Ìrúnú rẹ bò mí mọ́lẹ̀; ẹ̀rù rẹ sì bà mí dójú ikú. Wọ́n yí mi ká tọ̀sán-tòru bí ìṣàn omi ńlá; wọ́n ká mi mọ́ patapata. O ti mú kí ọ̀rẹ́ kòríkòsùn mi ati àwọn alábàárìn mi kọ̀ mí sílẹ̀; òkùnkùn nìkan ni ó yí mi ká níbi gbogbo.