ORIN DAFIDI 35:9-10

ORIN DAFIDI 35:9-10 YCE

Nígbà náà ni n óo máa yọ̀ ninu OLUWA, n óo sì yọ ayọ̀ ńlá nítorí ìgbàlà rẹ̀. N óo fi gbogbo ara wí pé, “OLUWA, ta ni ó dàbí rẹ? Ìwọ ni ò ń gba aláìlágbára lọ́wọ́ ẹni tí ó lágbára tí o sì ń gba aláìlágbára ati aláìní lọ́wọ́ ẹni tí ó fẹ́ fi wọ́n ṣe ìjẹ.”