ÌWÉ ÒWE 2:7-10

ÌWÉ ÒWE 2:7-10 YCE

Ó fún àwọn tí wọn dúró ṣinṣin ní ìjìnlẹ̀ ọgbọ́n, òun ni ààbò fún àwọn tí wọ́n ń rin ọ̀nà ẹ̀tọ́. Ó ń tọ́ wọn sí ìdájọ́ òtítọ́, ó sì ń pa ọ̀nà àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀ mọ́. Nígbà náà ni ìtumọ̀ òdodo ati ẹ̀tọ́ yóo yé ọ ati àìṣe ojuṣaaju, ati gbogbo ọ̀nà rere. Nítorí ọgbọ́n yóo wọnú ọkàn rẹ, ìmọ̀ yóo sì tu ẹ̀mí rẹ lára

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún ÌWÉ ÒWE 2:7-10

ÌWÉ ÒWE 2:7-10 - Ó fún àwọn tí wọn dúró ṣinṣin ní ìjìnlẹ̀ ọgbọ́n,
òun ni ààbò fún àwọn tí wọ́n ń rin ọ̀nà ẹ̀tọ́.
Ó ń tọ́ wọn sí ìdájọ́ òtítọ́,
ó sì ń pa ọ̀nà àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀ mọ́.
Nígbà náà ni ìtumọ̀ òdodo ati ẹ̀tọ́ yóo yé ọ
ati àìṣe ojuṣaaju, ati gbogbo ọ̀nà rere.
Nítorí ọgbọ́n yóo wọnú ọkàn rẹ,
ìmọ̀ yóo sì tu ẹ̀mí rẹ láraÌWÉ ÒWE 2:7-10 - Ó fún àwọn tí wọn dúró ṣinṣin ní ìjìnlẹ̀ ọgbọ́n,
òun ni ààbò fún àwọn tí wọ́n ń rin ọ̀nà ẹ̀tọ́.
Ó ń tọ́ wọn sí ìdájọ́ òtítọ́,
ó sì ń pa ọ̀nà àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀ mọ́.
Nígbà náà ni ìtumọ̀ òdodo ati ẹ̀tọ́ yóo yé ọ
ati àìṣe ojuṣaaju, ati gbogbo ọ̀nà rere.
Nítorí ọgbọ́n yóo wọnú ọkàn rẹ,
ìmọ̀ yóo sì tu ẹ̀mí rẹ lára