Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 146

1

Saamu 146:5

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ìbùkún ni fún ẹni tí Ọlọ́run Jakọbu ń ṣe ìrànlọ́wọ́ rẹ̀ tí ìrètí rẹ̀ wà nínú OLúWA Ọlọ́run rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 146:5

2

Saamu 146:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ẹ má ṣe ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú àwọn ọmọ-aládé, àní, ọmọ ènìyàn, lọ́wọ́ ẹni tí kò sí ìrànlọ́wọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 146:3

3

Saamu 146:7-8

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ẹni tí ń ṣe ìdájọ́ àwọn tí a ni lára, tí ó fi oúnjẹ fún àwọn tí ebi ń pa, OLúWA, tú àwọn oǹdè sílẹ̀, OLúWA mú àwọn afọ́jú ríran, OLúWA, gbé àwọn tí a rẹ̀ sílẹ̀ ga, OLúWA fẹ́ràn àwọn olódodo.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 146:7-8

4

Saamu 146:6

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ẹni tí ó dá ọ̀run àti ayé, òkun àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú wọn, ẹni tí ó pa òtítọ́ mọ́ títí ayé.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 146:6

5

Saamu 146:9

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA ń dá ààbò bo àwọn àlejò ó sì ń dá àwọn aláìní baba àti opó sí ṣùgbọ́n ó ba ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú jẹ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 146:9

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò