Saamu 146:7-8

Saamu 146:7-8 BMYO

Ẹni tí ń ṣe ìdájọ́ àwọn tí a ni lára, tí ó fi oúnjẹ fún àwọn tí ebi ń pa, OLúWA, tú àwọn oǹdè sílẹ̀, OLúWA mú àwọn afọ́jú ríran, OLúWA, gbé àwọn tí a rẹ̀ sílẹ̀ ga, OLúWA fẹ́ràn àwọn olódodo.