Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 145

1

Saamu 145:18

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA wà ní tòsí gbogbo àwọn tí ń ké pè é, sí gbogbo ẹni tí ń ké pè é ní òtítọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 145:18

2

Saamu 145:8

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Olóore-ọ̀fẹ́ ni OLúWA àti aláàánú ó lọ́ra láti bínú ó sì ní ìfẹ́ púpọ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 145:8

3

Saamu 145:9

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA dára sí ẹni gbogbo; ó ní àánú lórí ohun gbogbo tí ó dá.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 145:9

4

Saamu 145:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Títóbi ni OLúWA. Òun sì ni ó yẹ láti fi ìyìn fún púpọ̀púpọ̀: kò sí ẹni tí ó lè wọn títóbi rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 145:3

5

Saamu 145:13

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ìjọba rẹ ìjọba ayérayé ni, àti ìjọba rẹ wà ní gbogbo ìrandíran.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 145:13

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Saamu 145

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò