Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ Saamu 147

1

Saamu 147:3

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ó wo àwọn tí ọkàn wọ́n bàjẹ́ sàn ó sì di ọgbẹ́ wọ́n.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 147:3

2

Saamu 147:11

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA ni ayọ̀ nínú àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀, sí àwọn tí ó ní ìrètí nínú àánú rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 147:11

3

Saamu 147:5

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Títóbi ni Olúwa wa ó sì pọ̀ ní agbára òye rẹ̀ kò sì ní òpin.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 147:5

4

Saamu 147:4

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

Ó ka iye àwọn ìràwọ̀ ó sì pe ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní orúkọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 147:4

5

Saamu 147:6

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

BMYO

OLúWA wa pẹ̀lú àwọn onírẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni ó rẹ̀ àwọn ènìyàn búburú sílẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí Saamu 147:6

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò