Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 95

1

ORIN DAFIDI 95:6-7

Yoruba Bible

YCE

Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á jọ́sìn, kí á tẹríba, ẹ jẹ́ kí á kúnlẹ̀ níwájú OLUWA, Ẹlẹ́dàá wa! Nítorí òun ni Ọlọrun wa, àwa ni eniyan rẹ̀, tí ó ń kó jẹ̀ káàkiri, àwa ni agbo aguntan rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 95:6-7

2

ORIN DAFIDI 95:1-2

Yoruba Bible

YCE

Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á kọrin sí OLUWA; ẹ jẹ́ kí á hó ìhó ayọ̀ sí Olùdáàbòbò ati ìgbàlà wa! Ẹ jẹ́ kí á wá siwaju rẹ̀ pẹlu ọpẹ́; ẹ jẹ́ kí á fi orin ìyìn hó ìhó ayọ̀ sí i.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 95:1-2

3

ORIN DAFIDI 95:3

Yoruba Bible

YCE

Nítorí pé Ọlọrun tí ó tóbi ni OLUWA, ọba tí ó tóbi ni, ó ju gbogbo oriṣa lọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 95:3

4

ORIN DAFIDI 95:4

Yoruba Bible

YCE

Ìkáwọ́ rẹ̀ ni ọ̀gbun ilẹ̀ wà; gíga àwọn òkè ńlá wà ní ìkáwọ́ rẹ̀ pẹlu.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 95:4

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò