Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 96

1

ORIN DAFIDI 96:4

Yoruba Bible

YCE

Nítorí OLUWA tóbi, ó yẹ kí á máa yìn ín lọpọlọpọ; ó sì yẹ kí á bẹ̀rù rẹ̀ ju gbogbo oriṣa lọ.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 96:4

2

ORIN DAFIDI 96:2

Yoruba Bible

YCE

Ẹ kọ orin sí OLUWA, ẹ yin orúkọ rẹ̀; ẹ sọ nípa ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 96:2

3

ORIN DAFIDI 96:1

Yoruba Bible

YCE

Ẹ kọ orin titun sí OLUWA; gbogbo ayé, ẹ kọ orin sí OLUWA.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 96:1

4

ORIN DAFIDI 96:3

Yoruba Bible

YCE

Ẹ kéde ògo rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè; ẹ sọ̀rọ̀ iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 96:3

5

ORIN DAFIDI 96:9

Yoruba Bible

YCE

Ẹ sin OLUWA ninu ẹwà ìwà mímọ́; gbogbo ayé, ẹ wárìrì níwájú rẹ̀.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 96:9

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò