O. Daf 95:6-7
O. Daf 95:6-7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ wá, ẹ jẹ ki a wolẹ, ki a tẹriba: ẹ jẹ ki a kunlẹ niwaju Oluwa, Ẹlẹda wa. Nitori on li Ọlọrun wa; awa si li enia papa rẹ̀, ati agutan ọwọ rẹ̀. Loni bi ẹnyin o ba gbọ́ ohùn rẹ̀
Pín
Kà O. Daf 95O. Daf 95:6-7 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á jọ́sìn, kí á tẹríba, ẹ jẹ́ kí á kúnlẹ̀ níwájú OLUWA, Ẹlẹ́dàá wa! Nítorí òun ni Ọlọrun wa, àwa ni eniyan rẹ̀, tí ó ń kó jẹ̀ káàkiri, àwa ni agbo aguntan rẹ̀.
Pín
Kà O. Daf 95