Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Mọ ORIN DAFIDI 94

1

ORIN DAFIDI 94:19

Yoruba Bible

YCE

Nígbà tí àìbàlẹ̀ ọkàn mi pọ̀ pupọ, ìwọ ni o tù mí ninu, tí o dá mi lọ́kàn le.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 94:19

2

ORIN DAFIDI 94:18

Yoruba Bible

YCE

Nígbà tí mo rò pé, “Ẹsẹ̀ mi ti yọ̀,” OLUWA, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ni ó gbé mi ró.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 94:18

3

ORIN DAFIDI 94:22

Yoruba Bible

YCE

Ṣugbọn OLUWA ti di ibi ìsádi mi, Ọlọrun mi sì ti di àpáta ààbò mi.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 94:22

4

ORIN DAFIDI 94:12

Yoruba Bible

YCE

Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí o bá báwí, OLUWA, tí o sì kọ́ ní òfin rẹ

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 94:12

5

ORIN DAFIDI 94:17

Yoruba Bible

YCE

Bí kì í bá ṣe pé OLUWA ràn mí lọ́wọ́, ǹ bá ti dákẹ́ jẹ́ẹ́ ní isà òkú.

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 94:17

6

ORIN DAFIDI 94:14

Yoruba Bible

YCE

Nítorí OLUWA kò ní kọ àwọn eniyan rẹ̀ sílẹ̀; kò ní ṣá àwọn eniyan ìní rẹ̀ tì

Ṣe Àfiwé

Ṣàwárí ORIN DAFIDI 94:14

Abala Tó Kọjá
Abala tí ó Kàn
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò