Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Journey To The Manger

Ọjọ́ 24 nínú 70

Kì í se Omo ìkókó Mìíràn lásán

A kò tí lè bí omo ìkókó mìíràn lásán tí ìbí Rè, ayé, àti, ikú Rè ṣáájú nípa ọgọ́rùn-ún àsotélè.

A kò tí lè lóyún omo ìkókó mìíràn ni ònà tó jé àgbàyanu jù lo tó lè selè.

A kò tí lè bí omo ìkókó mìíràn tó ye fún ìkéède látódó ogun òrun.

A kò tí lè bí omo ìkókó mìíràn tó mú àwọn òlúsó àgùntàn níṣìírí tó jé pé wón fi àwọn àgùntàn wón sílè láti wá A.

A kò tí lè bí omo ìkókó mìíràn tí a sún àwọn okùnrin ológbón láti ìlà oòrùn láti bèrè ìwákiri láti wá A.

Omo ìkókó mìíràn kò lè mú èmígígùn Síméónì tó dúró ní láárí tàbí mú ìyìn sórí ètè Ánà.

Omo ìkókó mìíràn kò í ti lè dí okùnrin tó mú afójú ríran, mú adití gbọ́ ọ̀rọ̀, òmìnira fún àwọn tó lẹ́mìí èṣù, èmí sí àwon òkú, àti ìdáríjì fún ènì tá da lébi.

A kò tí lè bí Omo ìkókó mìíràn lásán kò í ti lè dí Òdó Àgùntàn Olórun tó má mú èsè aráyé lo.

Rárá,kì i se omo ìkókó mìíràn. Ó jé, Òun ni, àtipe máa má jé Jésù Kristi nígbà gbogbo, Oba àwọn Oba àti Olúwa àwọn Olúwa.

Isé Sisé: Kà ìtàn ìbílẹ̀ tí Ìhìn Rere Lúùkù (1:26-2:21).

Ìwé mímọ́

Nípa Ìpèsè yìí

Journey To The Manger

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì. 

More

A fé láti dúpé lówó Isé òjísé Touch fún ìpésé ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, E jòó ṣèbẹ̀wò visit: https://intouch.cc/yv18