Ìrìn àjò lo si Ìbùje EranÀpẹrẹ

Gbé Ìgbésí Eyé È Lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́ fún Un
Ìbí Jésù jé ìlérí ìrètí àti ìràpadà fún àwọn ènìyàn tó nílò Oba tuntun gidigidi. Ayé Rè jé gégé bí àpẹẹrẹ bí o se yé kí a tèlé Olórun Ni gbogbo ipò. Ikú Rè se pàṣípààrọ̀ fún àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ó fún wa láàyé láti mú wa padàbọ̀sípò ní ìbáṣepò wa pèlú Olórun. Àjíǹde Rè se ìmúse àwọn àsotélè ogbó àti ségun agbára èsè àti ikú. Àmó iṣẹ́ òjíṣẹ́ Jésù’ ré kọjá ààlà àwọn ìran títí láé àti o sì ñ yí aiyé pa dà lójoojúmó.
Olórun ràn Omo Rè sínú ayé ni ìgbà àkókó gégé bí omodé onírèlè, èyí gbéra ètò alágbára Rè tí ìràpadà. Jésù má tún padà wá gégé bí Oba aségun, èyí tí gbogbo ènîyàn yóò polongo Rè gégé bí Olúwa. Bí a se dúró dé ìpadà bò ìjagunmólú Rè, a lè gbé ìgbésí ayé wa fún Un bí ìsèdá tuntun, wá ààyè lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́..
Àtipe bí a se dára pò mó O nínú isé ìjoba ìmúpadàbọ̀sípò Rè tó tésíwájú títí di ojó ònìí, a bólá fún orúko Rè gégé bí Oba wa tí àwọn Oba àti Olúwa àwọn Olúwa.
Isé Sisé: Se isé kékeré ìmúpadàbọ̀sípò kan. mú ìdòtí kúrò nílẹ̀ èyí tí kì í ṣe tirè tàbí sètore àwọn ohun tó ní sí ilé ìtajà bọ́síkọ̀rọ̀ kan.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Ní alẹ́ ìdákẹ́ rọ́rọ́ kan ní ọdún 2000 sẹ́yìn, àwọn angẹli mu ìròyìn ìbí Olùgbàlà wá fún ẹgbẹ́ àwọn daran-daran kan níbi tí wọn ti ń da ẹran wọn. Lẹ́yìn tí wọ́n gbọ́ ìròyìn náà, àwọn daran-daran wọ̀nyí fi ohun gbogbo sí'lẹ̀ láti wá ìkókó tí ó wà ní ibùjẹ ẹran ní Bẹtilẹhẹmu. Lẹ́yìn gbogbo àwọn ọdún wọ̀nyí, ìpè yìí kò tíì yí padà. Ẹ̀ bá Dr. Charles Stanley rìn bí ó ṣe ń ràn yín l'ọ́wọ́ láti súnmọ́ Olùgbàlà, àti láti mú ọkàn yín le láti wá àyè láti sinmi nínú ìfẹ́ Bàbá ní àkókò yíì.
More