Jésù, mo nilo rẹÀpẹrẹ

Adura náà:
Jésù mo nilo rẹ! Ìwọ ni Olúwa, Ọlọrun mi, Ọba mi. Iwọ ni o yẹ láti gba gbogbo ìsìn mi. Ranmi lọwọ, nípa ore ọfẹ rẹ, láti mọ ọ ati lati féràn rẹ gidigidi, kí gbogbo nnkan ayé parẹ́, kí wọ́n sì di isuju simi.
Mo fẹ́ sìn ọ nikansoso. Mi o fẹ́ tẹlé àṣà. Mo wà nínú rẹ; mo fẹ láti di ọkan pẹ̀lúu rẹ̀. Di ọkàn mi pọ̀ pẹ̀lúu tirẹ, ki o sì fi otitọ rẹ sínúu mi.
Mo fẹ láti mọ Iwọ nìkan àti Ọrọ re, mo sì fẹ ní ipongbe láti fi ẹsẹ silẹ, kí n tẹle e àti Ọrọ rẹ. Ranmi lọwọ láti sìn ọ nínú emi àti ní otitọ.
Mo nilo agbára rẹ, ore ọfẹ rẹ àti ifẹ rẹ, ní ohunkóhun tí ìgbé ayé bá ti simi, kín un máa lè fesin sí ipò kọọkan, ènìyàn kọọkan àti ìdánwò kọọkan bí iwọ yóò ṣe fesin sií, fún gbogbo ògo rẹ.
Èmi kò fẹ́ fesin pẹ̀lú ojú lásán, ṣugbọn láti inú wá, láti odò omi ààyè. Mo fẹ sunmo ọ, Jésù, kí Emi rẹ ṣàn làti inúu mi nínú gbogbo ohun tí mo bá ṣe àti tí mo bá sọ.
Kí un rí gbogbo ayọ mi nínú ùn rẹ̀. Kí ayé è mi máa yin ọ l'ogo nínú gbogbo ohun tí mo bá sọ àti tí mo bá ṣe. (Orin Dáfídì 42:1-2a, Galatia 2:20). Níbikíbi tí mo bá wà, àti ohun kóhun tí mo bá nṣe, ẹsẹ Bíbélì tí mo bá nka tàbí orin tí mo bá nkọ, mo fẹ kí ọkàn mi, agbára a mi, àti ookan àyà mi fojusi ọ nìkan, lai fojusi ara mi àti ohun tí mo bá lakoja. Mo fẹ́ ọ àti iwọ nìkan ni mo fẹ́.
Bí mo bá
se àṣeyọrí tàbí mo bá kùnà,
bí mo bá yege tàbí mo pàdánù,
bí mo bá lówó tàbí ùn kò lówó,
bí a bá kami kun tàbí a kò kami kun,
bí a bá mọ mí tàbí a gbàgbé è mi,
kí un ní itẹlọrun nínú ìdánilójú pé o jẹ t'emi àti pé mo jẹ tìrẹ. Kí gbogbo ero mi jẹ́ láti fẹ́ ọ àti kí o fẹ́ mi, láti tẹ ọ lọrun àti sìn ọ.
Ranmi lọwọ láti rí ẹsẹ mi, láti kọ ọ sílẹ, pẹ̀lú ore ọfẹ rẹ. Ranmo l'ọwọ kí ebi òdodo máa pa mí àti kí un ní ipongbe fún òdodo. Jésù Olúwa, fún mi ní ore ọfẹ, aanu, àti ìfẹ́ rere kí un lè rí ọ, mọ ọ, fẹ́ ọ, àti jé òkan pẹ̀lúu rẹ.
Modupe nitori Ọrọ rẹ ṣọ fún mi pé tí mo bá bèèrè ohunkóhun ní orúkọ rẹ̀ e àti nínú ìfẹ è rẹ, wípé iwọ yóò ṣe. Amin. (Jòhánù 14:13-14)

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Njẹ iwọ mọ inilo Jésù lára? Ètò adura ọjọ́ méjì yí yíò ṣe imudara fún àsìkò idanikan wà pẹlu rẹ̀, yíò sì tún ràn ọ lọwọ láti ke pè é. Ètò adura ọjọ́ méjì yí tún jé ara ìpín kẹjọ "Jésù, mo nilo rẹ" láti ọwó iransẹ Thistlebend.
More
A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org