Jésù, mo nilo rẹÀpẹrẹ

Ni ayé òde òní a kún fún èrò ara tiwa nìkan, lai se àkíyèsí i rẹ, sùgbón ohun tí o yẹ ká gbìyànjú láti se ní kí a kún fún Kristi. Ní ọpọ ìgbà o má n soro láti mọ bí ọ̀nà wa se yatọ ṣí ọ̀nàa rẹ̀ nítorípé, kòsí bí irufẹ ilé tí a ti tọ wa dàgbà se rí, kristiani tàbí aise kristiani, nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí o n ngbe nínú u wa àti nítorípé a dàgbà sínú ìjọ tí o ti wọ inú àṣà, a ti kọ ìwà, ìsesí, èrò àpẹẹrẹ àti ọgbọn láti àwọn orísun tí kìí ṣe ti Jesu-Kristi, laimo.
Èyí ni èrò Pọọlù "Nítorí pé Kristi ni mo wà láàyè fún ní tèmi, bí mo bá sì kú, èrè ni ó jẹ́"
(Filipi 1:21). Pọọlù ko wà fún Kristi tẹlẹ. O bẹrẹ síi wà fún Kristi nígbàtí Jesu pàdée rẹ̀ ní orí ọnaa Damasku tí osi se ìdánilójú u ẹsẹ e rẹ̀ àti nípa ore ọfẹ a mú u láti rí Jésù bí ose rí.(Ìṣe àwọn Àpọsítélì 9:1-19). Jékí Jésù jẹ́ ádùrá rẹ, kí o sì ke pè é. Bèèrè fún agbára láti kọkọ wá ìjọba rẹ bí o ti pàṣẹ ni Matiu 6:25-33.
"Jésù, mo niloo rẹ. Mi kò le gbé ìgbésí ayé è mi láì sí iwọ.
Jésù, iwọ kìí se èrò lásán, àkójọ ise àti aimase, ẹkọ, tàbí ìdí ohun kan.
Mo nilo rẹ, mọ sì tún fẹ́ ọ! Mo fẹ́ mọ ọ gidigidi ju bí mo se mọ enikeni- àwọn ẹbí ì mi, ọrẹ e mi, ọrẹ timotimo, pẹlu araà mi.
Mo fẹ́ kí o wà pẹluu mi nibiyi, l'akoko yi. Mo nfẹ láti joko pẹlu rẹ, láti lo àkókò ní ìhà a rẹ, láti bèèrè àwọn ohun tí o njẹ́ mi l'ọkan. Mo fẹ́ kí n le sa tọ ọ, gbé orí mí lé àyàa rẹ, ki n sọ gbogbo ohun tí o wà l'ọkan mi, àti kí iwọ yí ọwọ́ rẹ yimi ká, kí o sọ òtítọ́ ṣí mi, àti àwọn ijinlẹ òtítọ́. Mo nilo iranlọwọ rẹ, ore ọfẹ rẹ, aanu rẹ. Èmi kò le dá gbé ilé ayé mi lásán.
Ṣe ìparí ètò yí lónì, kí o fi Matiu 6:25-33 gbàdúrà. A óò gbàdúrà míràn lọla tí iwọ lè máa gbà lójoojúmó títí di igbakuugba tí iwọ bá fẹ́ láti tẹ̀síwájú láti gbà ádùrá náà.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Njẹ iwọ mọ inilo Jésù lára? Ètò adura ọjọ́ méjì yí yíò ṣe imudara fún àsìkò idanikan wà pẹlu rẹ̀, yíò sì tún ràn ọ lọwọ láti ke pè é. Ètò adura ọjọ́ méjì yí tún jé ara ìpín kẹjọ "Jésù, mo nilo rẹ" láti ọwó iransẹ Thistlebend.
More
A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org