Idalare Nipa IgbagboÀpẹrẹ

Idalare Nipa Igbagbo

Ọjọ́ 6 nínú 7

Ti rapada Ko Eegun

Ohun to dára jùlọ ti ofin ẹsin lè fún wá ni ifisun ati ìdálẹbi. Àkolé di ẹni tí o mọ kúrò ninú ẹ̀ṣẹ̀ (ati ẹbi ẹ̀ṣẹ̀) nipa titẹle ofin ati ìrúbọ ẹsìn.

Síbẹ sibẹ, Kristi wà láti fún ọ ní ohùn to dára jùlọ, nipa ìrúbọ iku Rẹ, O ra ọ pàdà kúrò labẹ egún Ọlọrun, O ra ọ Kúrò labẹ egún ofin, o mú gbogbo ẹsun ati ìdálẹbi ẹ̀ṣẹ̀ kúrò, pẹlu, o ṣe ọ ní ajogún ìlérí. Vs. 13-14

Idariji ati ìgbàlà wá láti ọdọ Kristi nikan. Nínú Rẹ nikan ni ati ni ìràpadà ati iye ayérayé, igbekalẹ Ọlọrun ni yii fún Majẹmu Titun ati fún gbogbo ìgbà.

Ọlọrun ran Ọmọ Rẹ wá sáyé yìi, Kiiṣe lati wa dá ayé lẹbi ṣugbọn lati wá gbàá là, njẹ o ṣetan lati fi igbagbọ gbàá loni?

Siwaju kika: John 3:17, Iṣe 7:51,

Adura: Jésù, mo gbà Ọ lóni tókàn tókàn.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 5Ọjọ́ 7

Nípa Ìpèsè yìí

Idalare Nipa Igbagbo

Gbogbo eniyan ni afi fún lati de ipò ìdáláre, tá owá ni àlàáfíà pẹlu Ọlọrun ati ará wa, nínú ìmọ pé Ọlọrun ti dariji ọ ati pé otí pa gbogbo ifisun rẹ àti ìdálẹbi rẹ rẹ́, kó ni óhùn kán sí ọ ṣugbọn O ri ọ gẹgẹbi òdodo Rẹ, O fẹràn rẹ, òsì ni ọpọlọpọ ileri ti O fi pámọ́ fún ọ. Ìgbé ayé ìyanu ni eyi jẹ! Ṣugbọn kini a nilo lati lè gbé igbeaye yii tabi ṣe oṣe ṣe?

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL