Idalare Nipa IgbagboÀpẹrẹ

Idalare Nipa Igbagbo

Ọjọ́ 3 nínú 7

Abraham gẹgẹ bi Apẹẹrẹ Apeere

Abrahamu jẹ apẹrẹ ìgbàgbọ Kiiṣe ni akoko Majẹmu Lailai nìkan ṣùgbọ́n nínú Majẹmu Titun pelu ojẹ àpẹrẹ igbagbọ Vs.8 Bíbélì fi múlẹ̀ pẹ Abrahamu gbagbọ asi kàà sí òdodo fún.

To bẹ ti a ká orúkọ rẹ kun awọn to ṣe takuntakun nínú ìgbàgbọ nínú iwé Hébérù, a tọka sí gẹgẹbi "Bàbà Ìgbàgbọ".

Ni itokasi Abrahamu bíbélì wípé èrè wá fún ẹni tó nṣiṣẹ́ gẹgẹbi iṣẹ ti là kalẹ fún lati ṣe ṣugbọn a ká eré òdodo fún ẹni to gbagbọ ninù Ọlọrun tin dániláre.

Èwo lòó Yàn? Ṣé lati tẹle awọn agbekalẹ ofin ti yóò mú ọ ṣíṣe tíó lopin (Iṣẹ) tàbí kiõ fi irọrun gbà Ọlọrun gbọ kàsí dà ọ láre.

Ọlọrun ti là ọnà to rọrun julọ sí ìgbàlà, mú ìpinu rẹ kó tèlé ọnà náa lóni.

Siwaju kika: Heberu 11: 8-12, Roman 4:3-5.

Adura: OLÙWÀ, mò Yan lati tẹle ọnà igbagbọ to rọrun ti oti pèsè fún mí.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

Idalare Nipa Igbagbo

Gbogbo eniyan ni afi fún lati de ipò ìdáláre, tá owá ni àlàáfíà pẹlu Ọlọrun ati ará wa, nínú ìmọ pé Ọlọrun ti dariji ọ ati pé otí pa gbogbo ifisun rẹ àti ìdálẹbi rẹ rẹ́, kó ni óhùn kán sí ọ ṣugbọn O ri ọ gẹgẹbi òdodo Rẹ, O fẹràn rẹ, òsì ni ọpọlọpọ ileri ti O fi pámọ́ fún ọ. Ìgbé ayé ìyanu ni eyi jẹ! Ṣugbọn kini a nilo lati lè gbé igbeaye yii tabi ṣe oṣe ṣe?

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL