Àwon Òtá OkànÀpẹrẹ

Andy Staney: Àwọn ọ̀tá ọkàn náà<
Ètò ti Ọjọ́ kẹ́ta
“ Jíjọ̀wó̩ ọgbẹ́ àti ìbínú sílẹ̀
Ibi kíkà: Efeesu 4:25-32
ọ̀tá kejì tí ọkàn n naa ni ìbínú. A máa. n bí nú nígbà tí a ò bá rí ohun tí à ń fẹ́ gbà.
Fi oníbinú ènìyàn kan hàn mí un o sì fi ẹni ti a ti ṣa lọgbẹ́ ọkán hàn ọ́. Mo sì mú dáọ lójú pé a ti gba ohun kan lọ́wó̩ rẹ̀. Ẹnikan ń jẹ wọ́n ní gbèsè n kankan.
A sì mọ̀ àwọn eìyàn kan tí wọ́n le fi ìbínu wọn hàn ni ọ̀kan nínú àwọn ọ̀nà wọ̀n yí:"O jí ìjókọ mi lọ." "O jí ẹbí mi gbé. "Ọdún ayé mi tí ó dára jù ni o gbè lọ. "O jí ìgbéyàó mi gbé." " O fi àkókò ọ̀dọ́ mi dùn mí." "O lọ́ ìbálé mi gbà mọ́ mi lọ́wó̩.." "O jẹ mí ní ìlékún owó." "O jẹ mí ní ànfàní à ti gbìyànjú." “ O jẹ mí ní ànfàní à ti gbìyànjú lẹ́ẹ̀kejì si." “ O jẹ mí ní fífi ìfé̩hàn."
Gbòngbò ìbínú ni níní érò wípè ohun kan ti di mí mú lọ. Ohun kan ni a ń jẹ ọ́.Ní báyìí ìbáṣepọ̀ láàrín gbèsè àti ajẹgbèsè ti fo jú hàn kedere.Ìwọ ń kó̩? Igbèsè wo ló n fa ìbínú fún ọ?
Fún ígbàwo ni o fi gbà láààyè kí àwọn tí ó ṣá ọ lọ́gbẹ́ fi darí ayé rẹ? Fún Oṣù kan? Fún ọdún miràn? Fún ìgbà ayérẹ míràn? Fún ìgbà wo?
Mo fẹ́ dábá rẹ̀ péòní ni kí ó jé̩ ọjọ́ tí ìwọ yóò fi ìpalára yìí sílẹ̀!
Bí ó ti e jẹ́ pé. o kō lè yí ọwọ́ aago sé̩yìn. Ó jẹ́ òtítọ́ bákan náà pè o kò gbọdọ̀ jé̩kí ìà àtijọ́ darí ọjọ́ iwájú rẹ. Nínú ìwé Efesù Kẹ́rin, a paáláṣẹ láti “ mu Gbogbo ìwà kíkorò àti ìbínú, àti ìrunú, kúrò." A lè ṣe eléyìí nípa " dídá ríji ara wa, bí Jesu ṣe dárí jì ó̩."
Ìwòsàn ìbínú ni ìdáríjì. tí a bá fojú ṣọ́nà láti gbẹ̀san nítorí ohun āìtọ́ tí a ṣe sí wa, àwa ni a ó san ẹ̀an. Ní ìdàkejì té a bá fagilé àwọn gbèsè tí a jẹ wá, a ó gba òmìnira.
Nínú gbogbo ipá mé̩rẹ̀ẹ̀rin ti a ń ṣẹ àgbéyẹ̀wò nínú ètòyii, Mo ní ìgbàgbọ́ pé èyí- ìbínú tí kò lójú tùú láti inú ogbẹ́ àmọ̀ó̩mọ̀ tàbí aìmọ̀ó̩mọ̀-òun ló burú jù. Níọnà míràn ẹ̀wẹ̀ òun ni ó rọrùn jù láti borí. O nílò láti pinnu nénú ọkàn tẹ láti fagolé gbèsè náà. O innu O sì wíi, "O kò jẹ mí ní gbèsè ohun kan mó̩."
Tẹ̀lé Ìlànà mé̩rin yìí lónìí. (1) Ṣe àwárí ẹni tí o ń bínú sí. (2) Ṣe ìṣúná ohun ti wọ̀n jẹ ọ́. (3) Fagilé gbèsè náà nípa dídáríjì wó̩n. (4) Máṣe jẹ́kí ìbínú yìí gbilẹ̀ mọ́.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Gẹ́gẹ́ bíi ọkàn tí ara to méwulọ́wọ́ lè pa ara wa run, ọkàn tọ́ méwulọ́wọ́ nípa tí èrò - ìmọ̀lára àti nípa tẹ́mí lè pá ìwọ àti àwọn àjọṣe rè run. Fún ọjọ́ márùn-ún tó ń mbò, jẹ́ kí Andy Stanley rán ẹ lọ́wọ́ láti wò inú ara rè fún àwọn ọ̀tá ọkàn mẹ́rin tó wọ́pọ̀ — èbi, ìbínú, ojúkòkòrò, àti owú — àti pé kò ẹ bí ó máa ṣe yọ wón kúrò.
More