Àwon Òtá OkànÀpẹrẹ

Andy Stanley: Àwọn Ọ̀tá Ọkàn
Ìfọkànsìn Ojọ́ Kejì
“Jijẹ́wọ́”
Ìwé Mímọ́: 1 Jòhánù 1:5-10
Ọ̀tá ọkàn àkọ́kọ́ èbi. Ẹ̀bi ní àbájáde síse ohun tí a rò pé kò tọ̀nà. Ifìránṣẹ́ láti ọkàn tí ó wá pẹ̀lú ẹbí, “Mo je gbèsè!”
Ṣàyẹ̀wò ọkùnrin kan tó sáré lọ pẹ̀lú obìnrin mìíràn ó si fi àwọn ìdílé rè sílè. Láì mò nígbà náà, ó ti jí nǹkan kan láti ọ̀dọ̀ gbogbo ẹbí rẹ̀. Ó ti ja ìyàwó rè lólè ọjọ́ iwájú rè, ààbò níti ọ̀ràn-ìnáwó, àti orúkọ rere rè gẹ́gẹ́ bí ìyàwó. Láti ojú ìwòye àwọn ọmọ rẹ̀, ọkùnrin yìí já wón lólè Kérésìmesì wón, àwọn àṣà, èrò ìmọ̀lára àti ààbò níti ọ̀ràn-ìnáwó, ìbánisọ̀rọ̀pọ̀ àkókò oúnjẹ, pẹ̀lú ẹbí, àti bée bé lọ.
Báyìí, ọkùnrin tó ṣe gbogbo èyí kò ronú níti ohun tí ó ti gbà. Lákọ́kọ́, ó ronú níti ohun tí ó ti jèrè. Àmọ́ nígbà àkókò tí ọmọbìnrin rè kékeré béèrè lọ́wọ́ rè ìdí tí kò fi nífẹ̀ẹ́ Mọ́mì mo, ọkàn rè ru sókè. Ó máa débi fúnra rẹ. Dádì je gbèsè.
Kò sí ohun tó jú ní sísan gbèsè náà to máa mú ara tú ọkàn tá dá lẹ́bi lọ́wọ́ ìdààmú ìdálẹ́bi rè. Àwọn ènìyàn gbìyànjú láti síse láti káju rè, sin láti káju rè, fúnni láti káju rè, àti pé pàápàá gbàdúrà láti káju rè. Àmọ́ kò sí ìwà réré, láti ara ìlú lọ́wọ́, fífúnni olàwọ, tàbí àga ìjókòó ọjọ́ ìsinmi lè dèrò èbi. Gbèsè ní. Àtipe ẹnì gbọ́dọ̀ ṣàn tàbí páre fún ọkàn tó jẹ́ bí láti nírírí ìtúra.
Báwo ni ó sé lè pá èbi rè re? Ìdáhùn wá nínu oókan lára àwọn ẹsẹ Bíbélì tí mo há sórí ni ọmọdé: 1 Jòhánù 1:9. “tí a bá jẹ́ jẹ́wọ́ awọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, oun jẹ́ aṣeégbẹ́kẹ̀lé ati olódodo tí yoo fi dárí awọn ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá tí yoo sì wẹ̀ wá mọ́ kúrò ninu gbogbo àìṣòdodo”.
Ìjéwọ́ ní agbára láti tú èsè ká. Àti pé bí òpò òògùn ìtọ́jú ara, ó sise nígbà tí a bá lọ lọ́nà yíyẹ.Ìfisílò lọ́nà tọ́ yẹ máa ṣẹlẹ̀ nígbà tí a bá jẹ́wọ́ àwọn ẹsẹ wa, kì í ṣe sí Ọlọ́run nìkan, àmọ́ sí àwọn ènìyàn tí a tí ṣe lòdì sí.
Àwọn ènìyàn tí wọn jebi jẹ́ àwọn tí a tí dà lébi fún èsè kan náà. Níwọ̀n bí ó bá yín kọ́ àṣírí, níwón bí ó báa yín gbìyànjú láti dèrò ẹ̀rí ọkàn rè nípa tí tọrọ ìdáríjì lọ́wọ́ Ọlọ́run, ó ń fi ara rè lélẹ̀ láti tún ṣe ohun tó ti kọjá. Àmọ́ sá o, tí ó bá bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ́wọ́ àwon èsẹ̀ sí àwon tó tí sè lòdì sí, ó ṣeé ṣe pé ó kò ní padà àti tún se àwọn èsè yẹn.
Jẹ́wọ́ sí Ọlọ́run àti àwọn ẹlòmíràn bákan náà, àti pé ìwọ yóò pá ọ̀tá ọkàn rè yìí.
Kí ní ohun tó ń dá ọ ní èbi? Jẹ́wọ́ ẹsẹ̀ rè sí Ọlọ́run àti sí ẹnikẹ́ni tó tí pa lára. Se e lónìí.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Gẹ́gẹ́ bíi ọkàn tí ara to méwulọ́wọ́ lè pa ara wa run, ọkàn tọ́ méwulọ́wọ́ nípa tí èrò - ìmọ̀lára àti nípa tẹ́mí lè pá ìwọ àti àwọn àjọṣe rè run. Fún ọjọ́ márùn-ún tó ń mbò, jẹ́ kí Andy Stanley rán ẹ lọ́wọ́ láti wò inú ara rè fún àwọn ọ̀tá ọkàn mẹ́rin tó wọ́pọ̀ — èbi, ìbínú, ojúkòkòrò, àti owú — àti pé kò ẹ bí ó máa ṣe yọ wón kúrò.
More