Job 17:1-2
Job 17:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
EMI mi bajẹ, ọjọ mi parun, isa-okú duro dè mi. Nitõtọ! awọn ẹlẹya wà lọdọ mi, oju mi si tẹmọ́ imunibinu wọn.
Pín
Kà Job 17EMI mi bajẹ, ọjọ mi parun, isa-okú duro dè mi. Nitõtọ! awọn ẹlẹya wà lọdọ mi, oju mi si tẹmọ́ imunibinu wọn.