JOBU 17:1-2

JOBU 17:1-2 YCE

“Ọkàn mi bàjẹ́, ọjọ́ ayé mi ti dópin, ibojì sì ń dúró dè mí. Dájúdájú àwọn ẹlẹ́yà yí mi káàkiri, wọ́n ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́ lojukooju.