Job 17:1-2

Job 17:1-2 YBCV

EMI mi bajẹ, ọjọ mi parun, isa-okú duro dè mi. Nitõtọ! awọn ẹlẹya wà lọdọ mi, oju mi si tẹmọ́ imunibinu wọn.