Saamu 117:1

Saamu 117:1 YCB

Ẹ yin OLúWA, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn.