Ẹ ma yìn Oluwa, ẹnyin orilẹ-ède gbogbo: ẹ yìn i, ẹnyin enia gbogbo.
Ẹ máa yin OLUWA, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè! Ẹ yìn ín gbogbo ẹ̀yin eniyan
Ẹ yin OLúWA, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò