Ọlọ́rọ̀ àti tálákà péjọpọ̀: OLúWA ni ẹlẹ́dàá gbogbo wọn. Ọlọ́gbọ́n ènìyàn ti rí ibi tẹ́lẹ̀, ó ṣé ara rẹ̀ mọ́: ṣùgbọ́n àwọn òpè tẹ̀síwájú, a sì jẹ wọ́n ní yà. Èrè ìrẹ̀lẹ̀ àti ìbẹ̀rù OLúWA ni ọrọ̀ ọlá, àti ìyè.
Kà Òwe 22
Feti si Òwe 22
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Òwe 22:2-4
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò