ÌWÉ ÒWE 22:2-4

ÌWÉ ÒWE 22:2-4 YCE

Ọlọ́rọ̀ ati talaka pàdé, OLUWA ló dá ekinni-keji wọn. Ọlọ́gbọ́n rí ibi, ó farapamọ́, ṣugbọn òpè ń bá tirẹ̀ lọ láìbìkítà, ó sì kó sinu ìyọnu. Èrè ìrẹ̀lẹ̀ ati ìbẹ̀rù OLUWA ni ọrọ̀, ọlá, ati ìyè.