Matiu 5:7-10

Matiu 5:7-10 YCB

Alábùkún fún ni àwọn aláàánú, nítorí wọn yóò rí àánú gbà. Alábùkún fún ni àwọn ọlọ́kàn mímọ́, nítorí wọn yóò rí Ọlọ́run. Alábùkún fún ni àwọn onílàjà, nítorí ọmọ Ọlọ́run ni a ó máa pè wọ́n. Alábùkún fún ni àwọn ẹni tí a ṣe inúnibíni sí, nítorí tí wọ́n jẹ́ olódodo nítorí tiwọn ní ìjọba ọ̀run.

Àwọn fídíò fún Matiu 5:7-10

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Matiu 5:7-10

Matiu 5:7-10 - Alábùkún fún ni àwọn aláàánú,
nítorí wọn yóò rí àánú gbà.
Alábùkún fún ni àwọn ọlọ́kàn mímọ́,
nítorí wọn yóò rí Ọlọ́run.
Alábùkún fún ni àwọn onílàjà,
nítorí ọmọ Ọlọ́run ni a ó máa pè wọ́n.
Alábùkún fún ni àwọn ẹni tí a ṣe inúnibíni sí,
nítorí tí wọ́n jẹ́ olódodo
nítorí tiwọn ní ìjọba ọ̀run.Matiu 5:7-10 - Alábùkún fún ni àwọn aláàánú,

nítorí tiwọn ní ìjọba ọ̀run.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Matiu 5:7-10