Mat 5:7-10

Mat 5:7-10 YBCV

Alabukún-fun li awọn alãnu: nitori nwọn ó ri ãnu gbà. Alabukún-fun li awọn oninu-funfun: nitori nwọn ó ri Ọlọrun. Alabukún-fun li awọn onilaja: nitori ọmọ Ọlọrun ni a ó ma pè wọn. Alabukúnfun li awọn ẹniti a ṣe inunibini si nitori ododo: nitori tiwọn ni ijọba ọrun.

Àwọn fídíò fún Mat 5:7-10

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Mat 5:7-10

Mat 5:7-10 - Alabukún-fun li awọn alãnu: nitori nwọn ó ri ãnu gbà.
Alabukún-fun li awọn oninu-funfun: nitori nwọn ó ri Ọlọrun.
Alabukún-fun li awọn onilaja: nitori ọmọ Ọlọrun ni a ó ma pè wọn.
Alabukúnfun li awọn ẹniti a ṣe inunibini si nitori ododo: nitori tiwọn ni ijọba ọrun.Mat 5:7-10 - Alabukún-fun li awọn alãnu: nitori nwọn ó ri ãnu gbà.

Alabukúnfun li awọn ẹniti a ṣe inunibini si nitori ododo: nitori tiwọn ni ijọba ọrun.

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Mat 5:7-10