Matiu 22:30

Matiu 22:30 BMYO

Nítorí ní àjíǹde kò ní sí ìgbéyàwó, a kò sì ní fi í fún ni ní ìyàwó. Gbogbo ènìyàn yóò sì dàbí àwọn angẹli ní ọ̀run.

Àwọn fídíò fún Matiu 22:30