MATIU 22:30

MATIU 22:30 YCE

Nítorí pé ní àkókò ajinde kò ní sí pé à ń gbé iyawo, tabi pé à ń fi ọmọ fún ọkọ; nítorí bí àwọn angẹli ti rí ní ọ̀run ni wọn yóo rí.

Àwọn fídíò fún MATIU 22:30