Isaiah 33:5-6

Isaiah 33:5-6 BMYO

A gbé OLúWA ga, nítorí pé ó ń gbé ibi gíga, Òun yóò kún Sioni pẹ̀lú ẹ̀tọ́ àti òdodo. Òun yóò jẹ́ ìpìlẹ̀ tí ó dájú fún àkókò rẹ ibùjókòó ìgbàlà kíkún àti ọgbọ́n òun ìmọ̀; ìbẹ̀rù OLúWA ni kọ́kọ́rọ́ sí ìṣúra yìí.