AISAYA 33:5-6

AISAYA 33:5-6 YCE

A gbé OLUWA ga! Nítorí pé ibi gíga ni ó ń gbé; yóo mú kí ìdájọ́ òtítọ́ ati òdodo kún Sioni. Yóo mú kí ìdúróṣinṣin wà ní gbogbo àkókò rẹ̀. Yóo fún ọ ní ọpọlọpọ ìgbàlà, ati ọgbọ́n, ati ìmọ̀, ìbẹ̀rù OLUWA ni ìṣúra rẹ̀.