“Ọjọ́ náà ń bọ,” ni OLúWA wí, “tí ẹni tí ń tulẹ̀ yóò lé ẹni tí ń kórè bá Tí ẹni tí ń fún èso àjàrà yóò lé ẹni tí ń gbìn bá Àwọn òkè ńlá yóò sì kán ọtí wáìnì sílẹ̀ Tí yóò sì sàn láti ara àwọn òkè kéékèèkéé. Èmi yóò si tún mú ìgbèkùn Israẹli ènìyàn mi padà bọ̀.
Kà Amosi 9
Feti si Amosi 9
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Amosi 9:13-14
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò