Amosi 9:13

Amosi 9:13 YCB

“Ọjọ́ náà ń bọ,” ni OLúWA wí, “tí ẹni tí ń tulẹ̀ yóò lé ẹni tí ń kórè bá Tí ẹni tí ń fún èso àjàrà yóò lé ẹni tí ń gbìn bá Àwọn òkè ńlá yóò sì kán ọtí wáìnì sílẹ̀ Tí yóò sì sàn láti ara àwọn òkè kéékèèkéé.