Amosi 8:11

Amosi 8:11 BMYO

“Ọjọ́ ń bọ̀,” ni OLúWA Olódùmarè wí, “nígbà tí èmi yóò rán ìyàn sí ilẹ̀ náà, kì í ṣe ìyàn oúnjẹ tàbí òǹgbẹ fún omi. Ṣùgbọ́n ìyàn gbígbọ́ ọ̀rọ̀ OLúWA.