2 Samuẹli 22:7

2 Samuẹli 22:7 YCB

“Nínú ìpọ́njú mi, èmi ké pé OLúWA, èmi sì gbé ohùn mi sókè sí Ọlọ́run mi. Ó sí gbóhùn mi láti tẹmpili rẹ̀ igbe mí wọ etí rẹ̀.