SAMUẸLI KEJI 22:7

SAMUẸLI KEJI 22:7 YCE

Ninu ìpọ́njú mi, mo ké pe OLUWA mo ké pe Ọlọrun mi, ó gbọ́ ohùn mi láti inú tẹmpili rẹ̀; ó sì tẹ́tí sí igbe mi.