Àwọn ọmọ Jafani ni: Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu. Àwọn ọmọ Hamu ni: Kuṣi, Misraimu, Puti, àti Kenaani. Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Ṣabteka. Àwọn ọmọ Raama: Ṣeba àti Dedani. Kuṣi sì bí Nimrodu: Ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé. Misraimu sì bí Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu, Patrusimu, Kasluhimu, (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu.
Kà 1 Kronika 1
Feti si 1 Kronika 1
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: 1 Kronika 1:7-12
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò