O. Daf 65:1-2

O. Daf 65:1-2 YBCV

ỌLỌRUN, iyìn duro jẹ de ọ ni Sioni: ati si ọ li a o mu ileri ifẹ nì ṣẹ. Iwọ ti ngbọ́ adura, si ọdọ rẹ ni gbogbo enia mbọ̀.