O. Daf 65:1-2
O. Daf 65:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
ỌLỌRUN, iyìn duro jẹ de ọ ni Sioni: ati si ọ li a o mu ileri ifẹ nì ṣẹ. Iwọ ti ngbọ́ adura, si ọdọ rẹ ni gbogbo enia mbọ̀.
Pín
Kà O. Daf 65ỌLỌRUN, iyìn duro jẹ de ọ ni Sioni: ati si ọ li a o mu ileri ifẹ nì ṣẹ. Iwọ ti ngbọ́ adura, si ọdọ rẹ ni gbogbo enia mbọ̀.