O. Daf 47:6-7

O. Daf 47:6-7 YBCV

Ẹ kọrin iyìn si Ọlọrun, ẹ kọrin iyìn: ẹ kọrin iyìn si Ọba wa, ẹ kọrin iyìn. Nitori Ọlọrun li Ọba gbogbo aiye: ẹ fi oye kọrin iyìn.