O. Daf 135:13-14

O. Daf 135:13-14 YBCV

Oluwa, orukọ rẹ duro lailai; iranti rẹ Oluwa, lati iran-diran. Nitori ti Oluwa yio ṣe idajọ awọn enia rẹ̀, yio si ṣe iyọ́nu si awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀