Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

O. Daf 135:13-14

O. Daf 135:13-14 Bibeli Mimọ (YBCV)

Oluwa, orukọ rẹ duro lailai; iranti rẹ Oluwa, lati iran-diran. Nitori ti Oluwa yio ṣe idajọ awọn enia rẹ̀, yio si ṣe iyọ́nu si awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀

Pín
Kà O. Daf 135

O. Daf 135:13-14 Yoruba Bible (YCE)

OLUWA, orúkọ rẹ yóo wà títí lae, òkìkí rẹ óo sì máa kàn títí ayé. OLUWA yóo dá àwọn eniyan rẹ̀ láre, yóo sì ṣàánú àwọn iranṣẹ rẹ̀.

Pín
Kà O. Daf 135

O. Daf 135:13-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

OLúWA orúkọ rẹ dúró láéláé; ìrántí rẹ OLúWA, láti ìrandíran. Nítorí tí OLúWA yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀, yóò sì ṣe ìyọ́nú sí àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀.

Pín
Kà O. Daf 135
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò