O. Daf 131:2-3

O. Daf 131:2-3 YBCV

Nitõtọ emi mu ọkàn mi simi, mo si mu u dakẹjẹ, bi ọmọ ti a ti ọwọ iya rẹ̀ gbà li ẹnu ọmu: ọkàn mi ri bi ọmọ ti a já li ẹnu ọmu. Israeli, iwọ ni ireti lọdọ Oluwa lati isisiyi lọ ati lailai.